Lesson Notes By Weeks and Term - Primary 6

Agbara Ede Yoruba

Subject: Yoruba

Week 4

Topic: Agbara Ede Yoruba

Duration: 40 mins

Reference: Akotun Ede Yoruba fun ile iwe Alakoobere iwe kefa

Previous knowledge: Pupils are familiar with Onka

Objective: Lehin eko, aon akeeko gbodo mo Agbara ede Yoruba

Content

Ilo Ede ti Ona Daradara

Agbara wa ninu ede Yoruba ti a ba o daradara. Awon ona ti a le ede Yoruba lati fi tun ti eniyan seni nipa:

  1. Siso oro elomiran daradara
  2. A le fie de Yoruba wure fun eniyan
  3. A le fie de pon eniyan le
  4. A le fi ki eniyan
  5. A le fi ki eniyan ki ori re si wu
  6. A le lo ede Yoruba lati fi kewi

Awon to le wure ni:

  1. Agbalagba maa n wure fun omode
  2. Obi maa n wure fun omo
  3. Oga maa n wure fun omo ise
  4. Oluko le wure fun akekoo
  5. Onisegun le wure fun alaisan

Ona ti Yoruba ti n wure ni:

Ile Tuntun –Ile a tura

    Oo ni tode ruku wole

    Oo ni tile ruku rode

    Ile o ni gbona mo yin lara

Iyawo Tuntun-omo yoyo, nile aladi

    Ogede ki i gbodo ko yagan

    Oo fun soyun

    Oo feyin gbomo pon

Presentation:

Step I: Teacher revises previous lesson with pupils

Step II: Teacher introduces and explain new topic to pupils

Step III: Pupils are allowed to ask questions

Step IV: Teacher writes note on the boards for pupils

Evaluation:

  1. Daruko awon ibi marun-un ti a le se iwure
  2. ____________________ ni Yoruba n pe adura?

Conclusion: Teacher moves round for inspection, marking and correction of notes where necessary.



© Lesson Notes All Rights Reserved 2023