Week 3
Subject: Yoruba
Topic: Onka
Duration: 40 mins
Reference: Akotun Ede Yoruba fun ile iwe Alakobeere iwe kefa
Previous knowledge: Pupils are familiar with Ewi
Objective: Lehin eko, awon akeeko gbodo mo onka lati ookan – lelogorin de ogorun-un (81-100)
Content
Gege bi a ti salaye ni isaaju pe a maa n lo ogbon iropo ati iyokuro lati se onka. Bee gege naa ni a so pe a maa n lo ogbon ilopo (x) lati se onka. Ninu ogbon ilopo yii, a maa n lo ------ iye idi ogun lati se ilopo (20 x1). A si maan yo mewaa kuro ninu idi ogun, eyi ni a n pe ni aadin (20x1-10) bi apeere Aadota (20x3-10)
Aaro Kinni | Aaro Keji | |
81 (20 x 4)+1 | Ookanlelogorin | okanlelogorin |
82 (20x4)+2 | Eejilelogorin | ejilelogorin |
83 (20x4)+3 | Eetalelogorin | etalelogorin |
84 (20x4)+4 | Eerinlelogorin | erinlelogorin |
85 (20x5-10)-5 | aarundinlaadorun-un | arundinlaadorun-un |
86 (20x5-10)-4 | eerindinlaadorun-un | erindinlaadorun-un |
87 (20x5-10)-3 | eetadinlaadorun-un | etadinlaadorun-un |
88 (20x5-10)-2 | eejidinlaaadorun-un | ejidinlaadorun-un |
89 (20x5-10)-1 | Ookandinlaadorun | okandinlaadorun-un |
90 (20x5-10) | aadorun-un | adorun-un |
91 (20x5-10)+1 | ookanlelaadorun-un | okanlelaadorun-un |
92 (20x5-10)+2 | eejilelaadorun-un | ejilelaadorun-un |
93 (20x5-10)+3 | eetalelaadorun-un | etalelaadorun-un |
94 (20x5-10)+4 | eerinlelaadorun-un | erinlelaadorun-un |
95 (20x5)-5 | aarundinlogorun-un | arundinlogorun-un |
96 (20x5)-4 | eerindinlelogorun-un | erinlelelogorun-un |
97 (20x5)-3 | eetadinlogorun-un | etadinlogorun-un |
98 (20x5)-2 | eejidinlogorun-un | ejidinlogorun-un |
99 (20x5)-1 | ookandinlogorun-un | okandinlogorun-un |
100 (20x5) | Ogorun-un | Ogorun-un |
Presentation:
Step I: Teacher revises previous lesson with pupils
Step II: Teacher introduces and explains new topic to pupils
Step III: Pupils are allowed to ask questions
Step IV: Teacher writes notes on the board for pupils.
Evaluation:
Conclusion: Teacher moves round for inspection, marking and correction of notes where necessary.
© Lesson Notes All Rights Reserved 2023