Lesson Notes By Weeks and Term - Primary 6

Ewi

Week 2

Subject: Yoruba

Duration: 40 mins

Reference: Akotun Ede Yoruba fun ile� Eko Alakobeere, iwe kefa

Previous knowledge:Pupils are familiar with ise sise ati Ere re

Objective: Lehin eko, yii awon akekoo gbodo mo bi a ti n ki ewi

Content

Iwa rere leso eniyan

Iwa ! Iwa! Iwa

Iwa rere leso eniyan

Iwa loba awure

Bi o kole ogun

Bi o ni egbeegberun iwofa

Se arewa ni ti o ti on gun o garagara

Abi oko olowo iyebiye ti o ni

Oun ni o n jo o loju

Se nitori ipoola ti o wa

Ni o n mu o se igberaga

Ranti pea san bansa ni

Asan lori asan

Iwa rere la fi n lole aye gbo

Iwa loba awure

Presentation:

Step I: Teacher revises previous lesson with pupils

Step II: Teacher introduces and explains new topic for pupils

Step III: Pupils are allowed to ask questions

Step IV: Teacher writes notes on the board for pupils

Evaluation:

  1. Ki ni eso eniyan
  2. _________________ laba awure

Conclusion: Teacher moves round for inspection, marking and correction of notes where necessary.



� Lesson Notes All Rights Reserved 2023