Week 1
Subject: ��� Yoruba
Topic: ��� Ise sise ati Ere Re
Duration: ��� 40 mins
Reference: ��� Akotun Ede Yoruba fun ile-eko Alakoobere iwe kefa
Objective: ��� Leyin Eko awon akeeko gbodo mo
Content
Ninu gbogbo eya to wa ni agbaaye ti olorun da, yoruba feran ise lopolopo, won si korira ole tabi imele sise pupo. Idi ni eyi ti won fi maa n sope ise ni oogun ise. Eyi nipe, eni tiko ba fee kusee gbodo se ise. Eni ti ko ba ti se ise, dandan ni ku eni bee ya otosi.
Bi Yoruba se mu ise ni okunkundun yii, bee ni won korira ole tabi imele. Alapamasise ni Yoruba n pe eniyan to ya ole. A maa n sise ki ebi ma baa pa wa tebi tara. Oro Yoruba maa n sope iya ko leje eni ti o ba le sise, sugbon ebi ni yoo pa omo toba sole yato si ise agbe ni ile Yoruba, orisirisii awon ise isegun, ise aso hihun, ise ona, ise amokoko, aro dida abbl. Orisirisii ise igbalode si wa, bi, ise olukoni,aso reran, ajorinmorin, kolekole, onise ina abbl.
Iyi ise sise ati ere re
Abuku iwa ole
Presentation
Step 1: Teacher revises previous lesson with pupils
Step 2: Teacher introduces and explains new topic to pupils
Step 3: Pupils are allowed to ask question
Step 4: Teacher writes note on the board for pupils.
Evaluation
Conclusion: Teacher moves round for inspection, marking and correction of notes where necessary.
� Lesson Notes All Rights Reserved 2023