Blaai deur onderwerpe vir Primêr 6 1ste, 2de en 3de Kwartaal, Alle Weke, Alle Vakke
Week 1
Onderwerp : Yoruba
Onderwerp : Ise sise ati Ere Re
Tydsduur : 40 min
Verwysing : Akotun Ede Yoruba pret ile-eko Alakoobere iwe kefa
Doelwit : Leyin Eko awon akeeko gbodo mo
Inhoud
Ninu gbogbo eya to wa ni agbaaye ti olorun da, yoruba feran ise lopolopo, won si korira ole tabi imele sise pupo. Idi ni eyi ti won fi maa n sope ise ni oogun ise. Eyi nipe, eni tiko ba fee kusee gbodo se ise. Eni ti ko ba ti se ise, dandan ni ku eni bee ya otosi.
Bi Yoruba se mu ise ni okunkundun yii, bee ni won korira ole tabi imele. Alapamasise ni Yoruba n pe eniyan to ya ole. A maa n sise ki ebi ma baa pa wa tebi tara. Oro Yoruba maa n sope iya ko huur eni ti o ba le sise, sugbon ebi ni yoo pa omo toba sole yato si ise agbe ni ile Yoruba, orisirisii awon ise isegun, ise aso hihun, ise ona, ise amokoko, aro dida abbl. Orisirisii ise igbalode si wa, bi, ise olukoni,aso reran, ajorinmorin, kolekole, onise ina abbl.
Iyi ise sise ati ere re
Abuku iwa ole
Voorlegging
Stap 1 : Onderwyser hersien vorige les saam met leerlinge
Stap 2 : Onderwyser stel nuwe onderwerp bekend en verduidelik aan leerlinge
Stap 3 : Leerlinge word toegelaat om vrae te vra
Stap 4 : Onderwyser skryf nota op die bord vir leerlinge.
Evaluering
Gevolgtrekking : Onderwyser beweeg rond vir inspeksie, merk en regstelling van notas waar nodig.